ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 42:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 “Èmi Jèhófà, ti pè ọ́ nínú òdodo;

      Mo ti di ọwọ́ rẹ mú.

      Màá dáàbò bò ọ́, màá sì fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà+

      Àti bí ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

  • Mátíù 12:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ tí mo yàn, àyànfẹ́ mi, ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Màá fi ẹ̀mí mi sára rẹ̀,+ ó sì máa jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo ṣe kedere sí àwọn orílẹ̀-èdè.

  • Lúùkù 2:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 torí ojú mi ti rí ohun tí o máa fi gbani là,+

  • Lúùkù 2:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 ìmọ́lẹ̀+ láti mú ìbòjú kúrò lójú àwọn orílẹ̀-èdè+ àti ògo àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́