Jeremáyà 31:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá mú wọn pa dà wá láti ilẹ̀ àríwá.+ Màá sì kó wọn jọ láti ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+ Àwọn afọ́jú àti àwọn arọ máa wà lára wọn,+Aboyún àti ẹni tó ń rọbí, gbogbo wọn pa pọ̀. Bí ìjọ ńlá ni wọ́n máa pa dà sí ibí yìí.+
8 Màá mú wọn pa dà wá láti ilẹ̀ àríwá.+ Màá sì kó wọn jọ láti ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+ Àwọn afọ́jú àti àwọn arọ máa wà lára wọn,+Aboyún àti ẹni tó ń rọbí, gbogbo wọn pa pọ̀. Bí ìjọ ńlá ni wọ́n máa pa dà sí ibí yìí.+