-
Diutarónómì 30:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ì báà jẹ́ ìpẹ̀kun ọ̀run ni àwọn èèyàn rẹ tú ká sí, Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa kó ọ jọ, á sì mú ọ pa dà wá + láti ibẹ̀.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 20:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Èmi yóò mú yín jáde láàárín àwọn èèyàn, màá sì fi ọwọ́ agbára, apá tí mo nà jáde àti ìbínú kó yín jọ láti àwọn ilẹ̀ tí ẹ ti fọ́n ká sí.+
-