-
Àìsáyà 35:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Torí omi máa tú jáde ní aginjù,
Odò sì máa ṣàn ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú.
-
-
Àìsáyà 42:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ohun tí màá ṣe fún wọn nìyí, mi ò sì ní fi wọ́n sílẹ̀.”
-