-
Jeremáyà 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kálukú ń hùwà láìronú, wọn ò sì ní ìmọ̀.
-
-
Róòmù 1:21-23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nítorí bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n mọ Ọlọ́run, wọn ò yìn ín lógo bí Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, ìrònú wọn ò mọ́gbọ́n dání, ọkàn wọn tó ti kú tipiri sì ṣókùnkùn.+ 22 Bí wọ́n tiẹ̀ ń sọ pé àwọn jẹ́ ọlọ́gbọ́n, wọ́n ya òmùgọ̀, 23 wọ́n sì yí ògo Ọlọ́run tí kò lè díbàjẹ́ pa dà sí ohun tó dà bí àwòrán èèyàn tó lè díbàjẹ́ àti àwọn ẹyẹ àti àwọn ẹ̀dá ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin pẹ̀lú àwọn ẹran tó ń fàyà fà.*+
-