ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 12:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+

      Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+

      Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,

      Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+

  • Àìsáyà 51:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Òdodo mi sún mọ́lé.+

      Ìgbàlà mi máa jáde lọ,+

      Apá mi sì máa dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́.+

      Àwọn erékùṣù máa nírètí nínú mi,+

      Wọ́n sì máa dúró de apá* mi.

  • Àìsáyà 62:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé:

      “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,

      ‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+

      Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,

      Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́