ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 41:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+

      Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí.

  • Àìsáyà 43:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ,

      Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì, Olùgbàlà rẹ.

      Mo ti fi Íjíbítì ṣe ìràpadà fún ọ,

      Mo sì ti fi Etiópíà àti Sébà dípò rẹ.

  • Àìsáyà 44:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

      Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun:

      ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+

      Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́