-
Sáàmù 107:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ó ń sọ àwọn odò di aṣálẹ̀,
Ó sì ń sọ ìṣàn omi di ilẹ̀ tó gbẹ táútáú,+
-
Sáàmù 114:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
114 Nígbà tí Ísírẹ́lì jáde kúrò ní Íjíbítì,+
Tí ilé Jékọ́bù jáde kúrò lọ́dọ̀ àwọn tó ń sọ èdè àjèjì,
-
Àìsáyà 42:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Màá sọ àwọn òkè ńlá àti àwọn òkè kéékèèké di ahoro,
Màá sì mú kí gbogbo ewéko wọn gbẹ dà nù.
-
-
Náhúmù 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Báṣánì àti Kámẹ́lì rọ,+
Ìtànná Lẹ́bánónì sì rọ.
-
-
-
-
-