- 
	                        
            
            Sáàmù 107:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        33 Ó ń sọ àwọn odò di aṣálẹ̀, Ó sì ń sọ ìṣàn omi di ilẹ̀ tó gbẹ táútáú,+ - 
	                        
            
            Àìsáyà 44:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Ẹni tó ń sọ fún ibú omi pé, ‘Gbẹ, Màá sì mú kí gbogbo odò rẹ gbẹ táútáú’;+ 
 
- 
                                        
 
- 
	                        
            
            
 
-