Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Àìsáyà 53:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+
42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+