Sáàmù 102:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+Àkókò tí a dá ti pé.+ Àìsáyà 66:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí ìyá ṣe ń tu ọmọ rẹ̀ nínú,Bẹ́ẹ̀ ni màá máa tù yín nínú;+Ẹ sì máa rí ìtùnú torí Jerúsálẹ́mù.+ Jeremáyà 31:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+
13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+Àkókò tí a dá ti pé.+
12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+