-
Sáàmù 22:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Gbogbo ayé á rántí, wọ́n á sì yíjú sọ́dọ̀ Jèhófà.
Gbogbo ìdílé àwọn orílẹ̀-èdè á tẹrí ba níwájú rẹ.+
-
-
Àìsáyà 49:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó sọ pé: “Ti pé o jẹ́ ìránṣẹ́ mi nìkan ò tó,
Láti gbé àwọn ẹ̀yà Jékọ́bù dìde,
Kí o sì mú àwọn tí a dá sí lára Ísírẹ́lì pa dà.
-