Jẹ́nẹ́sísì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Jẹ́ ká+ dá èèyàn ní àwòrán wa,+ kí wọ́n jọ wá,+ kí wọ́n sì máa jọba lórí àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, àwọn ẹran ọ̀sìn, lórí gbogbo ayé àti lórí gbogbo ẹran tó ń rákò tó sì ń rìn lórí ilẹ̀.”+ Jòhánù 1:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, Ọ̀rọ̀ náà+ wà, Ọ̀rọ̀ náà sì wà pẹ̀lú Ọlọ́run,+ Ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ ọlọ́run kan.*+ 2 Ẹni yìí wà pẹ̀lú Ọlọ́run ní ìbẹ̀rẹ̀. Jòhánù 12:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Àìsáyà sọ àwọn nǹkan yìí torí pé ó rí ògo rẹ̀, ó sì sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀.+
26 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Jẹ́ ká+ dá èèyàn ní àwòrán wa,+ kí wọ́n jọ wá,+ kí wọ́n sì máa jọba lórí àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, àwọn ẹran ọ̀sìn, lórí gbogbo ayé àti lórí gbogbo ẹran tó ń rákò tó sì ń rìn lórí ilẹ̀.”+
1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, Ọ̀rọ̀ náà+ wà, Ọ̀rọ̀ náà sì wà pẹ̀lú Ọlọ́run,+ Ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ ọlọ́run kan.*+ 2 Ẹni yìí wà pẹ̀lú Ọlọ́run ní ìbẹ̀rẹ̀.