Ẹ́kísódù 15:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, ta ló dà bí rẹ nínú àwọn ọlọ́run?+ Ta ló dà bí rẹ, ìwọ tí o fi hàn pé ẹni mímọ́ jù lọ ni ọ́?+ Ẹni tó yẹ ká máa bẹ̀rù, ká máa fi orin yìn, Ẹni tó ń ṣe ohun ìyanu.+ Lúùkù 1:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Màríà wá sọ pé: “Ọkàn* mi gbé Jèhófà* ga,+ Lúùkù 1:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 torí pé Ẹni tó lágbára ti ṣe àwọn ohun ńláńlá fún mi, mímọ́ sì ni orúkọ rẹ̀+
11 Jèhófà, ta ló dà bí rẹ nínú àwọn ọlọ́run?+ Ta ló dà bí rẹ, ìwọ tí o fi hàn pé ẹni mímọ́ jù lọ ni ọ́?+ Ẹni tó yẹ ká máa bẹ̀rù, ká máa fi orin yìn, Ẹni tó ń ṣe ohun ìyanu.+