Àìsáyà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.
10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.