Àìsáyà 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹ wo bí ìlú olóòótọ́+ ṣe di aṣẹ́wó!+ Ìdájọ́ òdodo kún inú rẹ̀ tẹ́lẹ̀;+Òdodo ń gbé inú rẹ̀ nígbà kan,+Àmọ́ ní báyìí, àwọn apààyàn ló wà níbẹ̀.+ Àìsáyà 63:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+
21 Ẹ wo bí ìlú olóòótọ́+ ṣe di aṣẹ́wó!+ Ìdájọ́ òdodo kún inú rẹ̀ tẹ́lẹ̀;+Òdodo ń gbé inú rẹ̀ nígbà kan,+Àmọ́ ní báyìí, àwọn apààyàn ló wà níbẹ̀.+
10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+