ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 8:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Nígbà tí Séébà àti Sálímúnà sá, ó lé àwọn ọba Mídíánì méjèèjì bá, ó sì gbá wọn mú, ìyẹn Séébà àti Sálímúnà, jìnnìjìnnì sì bá gbogbo ibùdó náà.

  • Àwọn Onídàájọ́ 8:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ṣẹ́gun Mídíánì+ nìyẹn, wọn ò sì yọ wọ́n lẹ́nu* mọ́; àlàáfíà wá wà ní ilẹ̀ náà* fún ogójì (40) ọdún nígbà ayé Gídíónì.+

  • Àìsáyà 10:26, 27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa yọ pàṣán kan sí i,+ bó ṣe ṣe nígbà tó ṣẹ́gun Mídíánì lẹ́gbẹ̀ẹ́ àpáta Órébù.+ Ọ̀pá rẹ̀ máa wà lórí òkun, ó sì máa nà á sókè bó ṣe ṣe sí Íjíbítì.+

      27 Ní ọjọ́ yẹn, ẹrù rẹ̀ máa kúrò ní èjìká rẹ+

      Àti àjàgà rẹ̀ kúrò ní ọrùn rẹ,+

      Àjàgà náà sì máa ṣẹ́+ torí òróró.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́