ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 65:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Màá mú ọmọ* kan jáde látinú Jékọ́bù,

      Màá sì mú ẹni tó máa jogún àwọn òkè mi jáde látinú Júdà;+

      Àwọn àyànfẹ́ mi máa gbà á,

      Àwọn ìránṣẹ́ mi á sì máa gbé níbẹ̀.+

  • Hósíà 1:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Iye àwọn èèyàn* Ísírẹ́lì máa dà bí iyanrìn òkun tí a kò lè díwọ̀n tàbí tí a kò lè kà.+ Níbi tí a ti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kì í ṣe èèyàn mi,’+ a ó pè wọ́n ní, ‘Àwọn ọmọ Ọlọ́run alààyè.’+ 11 A ó sì mú kí àwọn èèyàn Júdà àti ti Ísírẹ́lì ṣọ̀kan,+ wọ́n á yan olórí fún ara wọn, wọ́n á sì jáde kúrò ní ilẹ̀ náà, nítorí ọjọ́ ńlá ni ọjọ́ náà máa jẹ́ ní Jésírẹ́lì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́