Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Jòhánù 1:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Jòhánù náà jẹ́rìí sí i, ó ní: “Mo rí i tí ẹ̀mí ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà láti ọ̀run, ó sì bà lé e.+ Ìṣe 10:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 nípa Jésù tó wá láti Násárẹ́tì, bí Ọlọ́run ṣe fi ẹ̀mí mímọ́+ àti agbára yàn án, tí ó sì lọ káàkiri ilẹ̀ náà, tí ó ń ṣe rere, tí ó sì ń wo gbogbo àwọn tí Èṣù ń ni lára sàn,+ torí pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀.+
42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
38 nípa Jésù tó wá láti Násárẹ́tì, bí Ọlọ́run ṣe fi ẹ̀mí mímọ́+ àti agbára yàn án, tí ó sì lọ káàkiri ilẹ̀ náà, tí ó ń ṣe rere, tí ó sì ń wo gbogbo àwọn tí Èṣù ń ni lára sàn,+ torí pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀.+