Sáàmù 137:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+ Jeremáyà 51:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Bábílónì á sì di òkìtì òkúta,+Ibùgbé àwọn ajáko,*+Ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé,Tí ẹnì kankan kò ní gbé ibẹ̀.+ Ìfihàn 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó sì fi ohùn tó le ké jáde pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá ti ṣubú,+ ó sì ti di ibi tí àwọn ẹ̀mí èṣù ń gbé àti ibi tí gbogbo ẹ̀mí àìmọ́* àti gbogbo ẹyẹ àìmọ́ tí a kórìíra ń lúgọ sí!+
8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+
37 Bábílónì á sì di òkìtì òkúta,+Ibùgbé àwọn ajáko,*+Ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé,Tí ẹnì kankan kò ní gbé ibẹ̀.+
2 Ó sì fi ohùn tó le ké jáde pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá ti ṣubú,+ ó sì ti di ibi tí àwọn ẹ̀mí èṣù ń gbé àti ibi tí gbogbo ẹ̀mí àìmọ́* àti gbogbo ẹyẹ àìmọ́ tí a kórìíra ń lúgọ sí!+