ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 21:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi:

      Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,

      Apanirun sì ń pani run.

      Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+

      Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+

  • Jeremáyà 50:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Nítorí wò ó, màá gbé àwọn orílẹ̀-èdè ńlá dìde láti ilẹ̀ àríwá

      Màá sì mú kí wọ́n gbéjà ko Bábílónì.+

      Wọ́n á tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti gbógun tì í;

      Ibẹ̀ ni wọ́n á ti gbà á.

      Ọfà wọn dà bíi ti jagunjagun

      Tó ń múni ṣòfò ọmọ;+

      Wọn kì í pa dà wá lọ́wọ́ òfo.

  • Jeremáyà 51:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.*

      Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+

      Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run.

      Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.

  • Dáníẹ́lì 5:30, 31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Òru ọjọ́ yẹn gan-an ni wọ́n pa Bẹliṣásárì, ọba àwọn ará Kálídíà.+ 31 Dáríúsì + ará Mídíà sì gba ìjọba; ọjọ́ orí rẹ̀ jẹ́ nǹkan bí ọdún méjìlélọ́gọ́ta (62).

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́