-
Sáàmù 48:1-3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Jèhófà tóbi, òun sì ni ìyìn yẹ jù lọ
Ní ìlú Ọlọ́run wa, ní òkè mímọ́ rẹ̀.
-
-
Sáàmù 132:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Ibi ìsinmi mi títí láé nìyí;
Ibí ni màá máa gbé,+ nítorí ohun tí mo fẹ́ nìyẹn.
-