- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti wá gbéjà kò ó láti àríwá.+ Ó ti sọ ilẹ̀ rẹ̀ di ohun àríbẹ̀rù; Kò sì sí ẹni tó ń gbé inú rẹ̀. Èèyàn àti ẹranko ti fẹsẹ̀ fẹ; Wọ́n ti lọ.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Nítorí wò ó, màá gbé àwọn orílẹ̀-èdè ńlá dìde láti ilẹ̀ àríwá Màá sì mú kí wọ́n gbéjà ko Bábílónì.+ Wọ́n á tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti gbógun tì í; Ibẹ̀ ni wọ́n á ti gbà á. 
 
-