Jẹ́nẹ́sísì 10:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+ 3 Àwọn ọmọ Gómérì ni Áṣíkénásì,+ Rífátì àti Tógámà.+ Jeremáyà 50:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Wò ó! Àwọn èèyàn kan ń wọlé bọ̀ láti àríwá;Orílẹ̀-èdè ńlá àti àwọn atóbilọ́lá ọba+ ni a ó gbé dìdeLáti àwọn ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+
2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+ 3 Àwọn ọmọ Gómérì ni Áṣíkénásì,+ Rífátì àti Tógámà.+
41 Wò ó! Àwọn èèyàn kan ń wọlé bọ̀ láti àríwá;Orílẹ̀-èdè ńlá àti àwọn atóbilọ́lá ọba+ ni a ó gbé dìdeLáti àwọn ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+