Àìsáyà 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn. Jeremáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀. Jeremáyà 51:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Àwọn ọ̀run àti ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú wọnMáa kígbe ayọ̀ lórí Bábílónì,+Nítorí pé àwọn apanirun máa wá bá a láti àríwá,”+ ni Jèhófà wí.
17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn.
11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.
48 Àwọn ọ̀run àti ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú wọnMáa kígbe ayọ̀ lórí Bábílónì,+Nítorí pé àwọn apanirun máa wá bá a láti àríwá,”+ ni Jèhófà wí.