Àìsáyà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+ Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì. Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀. Àìsáyà 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní ọjọ́ yẹn, Íjíbítì máa dà bí obìnrin, ó máa gbọ̀n rìrì, ẹ̀rù á sì máa bà á torí ọwọ́ ìhàlẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gbé sókè sí i.+
19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+ Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì. Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀.
16 Ní ọjọ́ yẹn, Íjíbítì máa dà bí obìnrin, ó máa gbọ̀n rìrì, ẹ̀rù á sì máa bà á torí ọwọ́ ìhàlẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun gbé sókè sí i.+