Jeremáyà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lẹ́yìn náà, mo mú yín wá sí ilẹ̀ eléso,Kí ẹ lè máa jẹ èso rẹ̀ àti àwọn ohun rere rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n ẹ wọlé wá, ẹ sì sọ ilẹ̀ mi di ẹlẹ́gbin;Ẹ sọ ogún mi di ohun ìríra.+ Hósíà 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn èèyàn mi ti pinnu láti jẹ́ aláìṣòótọ́ sí mi.+ Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n pè wọ́n sókè,* kò sí ẹnì kankan tó dìde.
7 Lẹ́yìn náà, mo mú yín wá sí ilẹ̀ eléso,Kí ẹ lè máa jẹ èso rẹ̀ àti àwọn ohun rere rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n ẹ wọlé wá, ẹ sì sọ ilẹ̀ mi di ẹlẹ́gbin;Ẹ sọ ogún mi di ohun ìríra.+
7 Àwọn èèyàn mi ti pinnu láti jẹ́ aláìṣòótọ́ sí mi.+ Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n pè wọ́n sókè,* kò sí ẹnì kankan tó dìde.