Léfítíkù 26:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àmọ́ láìka gbogbo èyí sí, nígbà tí wọ́n ṣì wà ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn, mi ò ní kọ̀ wọ́n pátápátá+ tàbí kí n ta wọ́n nù débi pé màá pa wọ́n run pátápátá, torí ìyẹn á da májẹ̀mú tí mo bá wọn dá,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn. Jeremáyà 10:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jèhófà, fi ìdájọ́ tọ́ mi sọ́nà,Àmọ́ kì í ṣe nínú ìbínú rẹ,+ kí o má bàa pa mí run.+
44 Àmọ́ láìka gbogbo èyí sí, nígbà tí wọ́n ṣì wà ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn, mi ò ní kọ̀ wọ́n pátápátá+ tàbí kí n ta wọ́n nù débi pé màá pa wọ́n run pátápátá, torí ìyẹn á da májẹ̀mú tí mo bá wọn dá,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn.