Àìsáyà 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+ Àìsáyà 14:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Màá dìde sí wọn,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “Màá pa orúkọ àti àṣẹ́kù run, màá sì pa àtọmọdọ́mọ àti ìran tó ń bọ̀ run kúrò ní Bábílónì,”+ ni Jèhófà wí. Àìsáyà 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+
19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+
22 “Màá dìde sí wọn,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “Màá pa orúkọ àti àṣẹ́kù run, màá sì pa àtọmọdọ́mọ àti ìran tó ń bọ̀ run kúrò ní Bábílónì,”+ ni Jèhófà wí.
9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+