Àìsáyà 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Òmùgọ̀ ni àwọn olórí Sóánì.+ Ìmọ̀ràn tí kò bọ́gbọ́n mu làwọn tó gbọ́n jù nínú àwọn agbani-nímọ̀ràn Fáráò ń mú wá.+ Báwo lẹ ṣe máa sọ fún Fáráò pé: “Àtọmọdọ́mọ àwọn ọlọ́gbọ́n ni mí,Àtọmọdọ́mọ àwọn ọba àtijọ́”? Ìsíkíẹ́lì 30:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá pa Pátírọ́sì+ run, màá dá iná sí Sóánì, màá sì dá Nóò* lẹ́jọ́.+
11 Òmùgọ̀ ni àwọn olórí Sóánì.+ Ìmọ̀ràn tí kò bọ́gbọ́n mu làwọn tó gbọ́n jù nínú àwọn agbani-nímọ̀ràn Fáráò ń mú wá.+ Báwo lẹ ṣe máa sọ fún Fáráò pé: “Àtọmọdọ́mọ àwọn ọlọ́gbọ́n ni mí,Àtọmọdọ́mọ àwọn ọba àtijọ́”?