Àìsáyà 55:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+ Jóẹ́lì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Síbẹ̀, ẹ fi gbogbo ọkàn yín pa dà sọ́dọ̀ mi báyìí,” ni Jèhófà wí,+“Kí ẹ gbààwẹ̀,+ kí ẹ sunkún, kí ẹ sì pohùn réré ẹkún.
7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+
12 “Síbẹ̀, ẹ fi gbogbo ọkàn yín pa dà sọ́dọ̀ mi báyìí,” ni Jèhófà wí,+“Kí ẹ gbààwẹ̀,+ kí ẹ sunkún, kí ẹ sì pohùn réré ẹkún.