Sáàmù 46:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ọlọ́run ni ibi ààbò wa àti okun wa,+Ìrànlọ́wọ́ tó wà lárọ̀ọ́wọ́tó ní àkókò wàhálà.+ Náhúmù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà jẹ́ ẹni rere,+ odi agbára ní ọjọ́ wàhálà.+ Ó sì mọ* àwọn tó ń wá ibi ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀.+