Sáàmù 107:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí àwọn tí Jèhófà gbà* pa dà sọ bẹ́ẹ̀,Àwọn tó gbà pa dà lọ́wọ́* ọ̀tá,+ 3 Àwọn tó kó jọ láti àwọn ilẹ̀,+Láti ìlà oòrùn àti láti ìwọ̀ oòrùn,*Láti àríwá àti láti gúúsù.+ Àìsáyà 62:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n máa pè wọ́n ní àwọn èèyàn mímọ́, àwọn tí Jèhófà tún rà,+A sì máa pè ọ́ ní Ẹni Tí A Wá, Ìlú Tí A Kò Pa Tì.+
2 Kí àwọn tí Jèhófà gbà* pa dà sọ bẹ́ẹ̀,Àwọn tó gbà pa dà lọ́wọ́* ọ̀tá,+ 3 Àwọn tó kó jọ láti àwọn ilẹ̀,+Láti ìlà oòrùn àti láti ìwọ̀ oòrùn,*Láti àríwá àti láti gúúsù.+
12 Wọ́n máa pè wọ́n ní àwọn èèyàn mímọ́, àwọn tí Jèhófà tún rà,+A sì máa pè ọ́ ní Ẹni Tí A Wá, Ìlú Tí A Kò Pa Tì.+