- 
	                        
            
            Àìsáyà 8:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ó máa wá sórí gbogbo ibi tí omi rẹ̀ ń ṣàn gbà, Ó máa kún bo gbogbo bèbè rẹ̀, 8 Ó sì máa rọ́ gba Júdà kọjá. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Àìsáyà 10:28-32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        29 Wọ́n ti kọjá níbi tó ṣeé fẹsẹ̀ gbà nínú odò; Gébà+ ni wọ́n sùn mọ́jú; 30 Kígbe kí o sì pariwo, ìwọ ọmọbìnrin Gálímù! Fiyè sílẹ̀, ìwọ Láíṣà! O gbé, ìwọ Ánátótì!+ 31 Mádíménà ti sá lọ. Àwọn tó ń gbé Gébímù ti wá ibì kan fara pa mọ́ sí. 32 Lónìí yìí gan-an, ó máa dúró ní Nóbù.+ Ó mi ẹ̀ṣẹ́ rẹ̀ sí òkè ọmọbìnrin Síónì, Òkè kékeré Jerúsálẹ́mù. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Àìsáyà 33:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Àwọn ojú pópó dá páropáro; Ẹnì kankan ò gba àwọn ojú ọ̀nà kọjá. 
 
-