Jeremáyà 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́,+Àwọn àlùfáà sì ń fi àṣẹ wọn tẹ àwọn èèyàn lórí ba. Àwọn èèyàn mi sì fẹ́ ẹ bẹ́ẹ̀.+ Àmọ́, kí lẹ máa ṣe nígbà tí òpin bá dé?” Hábákúkù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá. Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+
31 Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́,+Àwọn àlùfáà sì ń fi àṣẹ wọn tẹ àwọn èèyàn lórí ba. Àwọn èèyàn mi sì fẹ́ ẹ bẹ́ẹ̀.+ Àmọ́, kí lẹ máa ṣe nígbà tí òpin bá dé?”
4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá. Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+