ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,

      Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+

      Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+

      Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+

      Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+

  • Àìsáyà 58:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 ‘Kí ló dé tí o ò rí i nígbà tí à ń gbààwẹ̀?+

      Kí ló sì dé tí o ò kíyè sí i nígbà tí à ń pọ́n ara* wa lójú?’+

      Torí ní ọjọ́ tí ẹ̀ ń gbààwẹ̀, ire* ara yín lẹ̀ ń wá,

      Ẹ sì ń fìyà jẹ àwọn alágbàṣe yín.+

  • Jeremáyà 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá mú àjálù+ tí wọn kò ní lè bọ́ nínú rẹ̀ wá bá wọn. Nígbà tí wọ́n bá ké pè mí fún ìrànlọ́wọ́, mi ò ní fetí sí wọn.+

  • Ìsíkíẹ́lì 8:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Torí náà, màá bínú sí wọn. Mi ò ní ṣàánú wọn, mi ò sì ní yọ́nú sí wọn.+ Bí wọ́n bá tiẹ̀ kígbe tantan kí n lè gbọ́, mi ò ní dá wọn lóhùn.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́