ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 87:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Àwọn ohun ológo ni wọ́n ń sọ nípa rẹ, ìwọ ìlú Ọlọ́run tòótọ́.+ (Sélà)

  • Ìsíkíẹ́lì 43:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ó sọ fún mi pé:

      “Ọmọ èèyàn, ibi ìtẹ́ mi+ àti ibi tí màá gbé ẹsẹ̀ mi sí nìyí,+ ibẹ̀ ni èmi yóò máa gbé títí láé láàárín àwọn èèyàn Ísírẹ́lì.+ Ilé Ísírẹ́lì àti àwọn ọba wọn kò ní fi àgbèrè ẹ̀sìn tí wọ́n ń ṣe àti òkú àwọn ọba wọn nígbà tí wọ́n bá kú sọ orúkọ mímọ́ mi di ẹlẹ́gbin mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́