-
Sáàmù 68:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Dájúdájú, Jèhófà yóò máa gbé ibẹ̀ títí láé.+
-
-
Sáàmù 132:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Ibi ìsinmi mi títí láé nìyí;
Ibí ni màá máa gbé,+ nítorí ohun tí mo fẹ́ nìyẹn.
-