- 
	                        
            
            Émọ́sì 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 ‘Màá gbìn wọ́n sórí ilẹ̀ wọn, A kò sì ní fà wọ́n tu mọ́ Kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ wí.” 
 
- 
                                        
15 ‘Màá gbìn wọ́n sórí ilẹ̀ wọn,
A kò sì ní fà wọ́n tu mọ́
Kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ wí.”