ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ta ni nínú yín tó jẹ́ èèyàn rẹ̀? Kí Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀, kí ó lọ sí Jerúsálẹ́mù tó wà ní Júdà, kí ó sì tún ilé Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì kọ́, òun ni Ọlọ́run tòótọ́, tí ilé rẹ̀ wà ní Jerúsálẹ́mù.*

  • Jeremáyà 12:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àmọ́ lẹ́yìn tí mo bá fà wọ́n tu, màá tún ṣàánú wọn, màá sì mú kálukú wọn pa dà sí ogún rẹ̀ àti sí ilẹ̀ rẹ̀.”

  • Jeremáyà 25:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbogbo ilẹ̀ yìí á di àwókù àti ohun àríbẹ̀rù, àwọn orílẹ̀-èdè yìí á sì ní láti fi àádọ́rin (70) ọdún sin ọba Bábílónì.”’+

  • Jeremáyà 29:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Tó bá ti pé àádọ́rin (70) ọdún tí ẹ ti wà ní Bábílónì, màá yí ojú mi sí yín,+ màá sì mú ìlérí mi ṣẹ láti mú yín pa dà wá sí ibí yìí.’+

  • Ìsíkíẹ́lì 36:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Èmi yóò kó yín látinú àwọn orílẹ̀-èdè, màá pa dà kó yín jọ láti gbogbo ilẹ̀, màá sì mú yín wá sórí ilẹ̀ yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́