Jeremáyà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wò ó, mo ti fàṣẹ yàn ọ́ lónìí lórí àwọn orílẹ̀-èdè àti lórí àwọn ìjọba, láti fà tu àti láti bì wó, láti pa run àti láti ya lulẹ̀, láti kọ́ àti láti gbìn.”+ Jeremáyà 30:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó, màá kó àwọn tó lọ sí oko ẹrú láti àgọ́ Jékọ́bù jọ,+Máa sì ṣojú àánú sí àwọn àgọ́ ìjọsìn rẹ̀. Wọ́n á tún ìlú náà kọ́ sórí òkìtì rẹ̀,+Ibi tó sì yẹ ni wọ́n á kọ́ ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò sí. Jeremáyà 32:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ṣe ni inú mi á máa dùn nítorí wọn láti máa ṣe rere fún wọn,+ màá sì fi gbogbo ọkàn mi àti gbogbo ara* mi gbìn wọ́n sí ilẹ̀ yìí.’”+
10 Wò ó, mo ti fàṣẹ yàn ọ́ lónìí lórí àwọn orílẹ̀-èdè àti lórí àwọn ìjọba, láti fà tu àti láti bì wó, láti pa run àti láti ya lulẹ̀, láti kọ́ àti láti gbìn.”+
18 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó, màá kó àwọn tó lọ sí oko ẹrú láti àgọ́ Jékọ́bù jọ,+Máa sì ṣojú àánú sí àwọn àgọ́ ìjọsìn rẹ̀. Wọ́n á tún ìlú náà kọ́ sórí òkìtì rẹ̀,+Ibi tó sì yẹ ni wọ́n á kọ́ ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò sí.
41 Ṣe ni inú mi á máa dùn nítorí wọn láti máa ṣe rere fún wọn,+ màá sì fi gbogbo ọkàn mi àti gbogbo ara* mi gbìn wọ́n sí ilẹ̀ yìí.’”+