Àìsáyà 30:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìmọ́lẹ̀ òṣùpá àrànmọ́jú máa dà bí ìmọ́lẹ̀ oòrùn; ìmọ́lẹ̀ oòrùn sì máa lágbára sí i ní ìlọ́po méje,+ bí ìmọ́lẹ̀ ọjọ́ méje, ní ọjọ́ tí Jèhófà bá di àfọ́kù àwọn èèyàn rẹ̀,*+ tó sì wo ọgbẹ́ ńlá tó dá sí wọn lára nígbà tó kọ lù wọ́n sàn.+ Jeremáyà 30:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Ṣùgbọ́n màá mú ọ lára dá, màá sì wo ọgbẹ́ rẹ sàn,”+ ni Jèhófà wí,“Bí wọ́n tiẹ̀ pè ọ́ ní ẹni ìtanù: ‘Síónì, tí ẹnikẹ́ni kò fẹ́.’”+
26 Ìmọ́lẹ̀ òṣùpá àrànmọ́jú máa dà bí ìmọ́lẹ̀ oòrùn; ìmọ́lẹ̀ oòrùn sì máa lágbára sí i ní ìlọ́po méje,+ bí ìmọ́lẹ̀ ọjọ́ méje, ní ọjọ́ tí Jèhófà bá di àfọ́kù àwọn èèyàn rẹ̀,*+ tó sì wo ọgbẹ́ ńlá tó dá sí wọn lára nígbà tó kọ lù wọ́n sàn.+
17 “Ṣùgbọ́n màá mú ọ lára dá, màá sì wo ọgbẹ́ rẹ sàn,”+ ni Jèhófà wí,“Bí wọ́n tiẹ̀ pè ọ́ ní ẹni ìtanù: ‘Síónì, tí ẹnikẹ́ni kò fẹ́.’”+