Jeremáyà 31:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+
12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+