-
Jóṣúà 19:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ààlà náà sì dé Tábórì,+ Ṣáhásúmà àti Bẹti-ṣémẹ́ṣì, ààlà wọn wá parí sí Jọ́dánì, gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún (16) pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-