- 
	                        
            
            Ìsíkíẹ́lì 25:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èrò ìkà tó wà lọ́kàn àwọn Filísínì* ti mú kí wọ́n máa wá bí wọ́n á ṣe gbẹ̀san kí wọ́n sì pani run, torí wọn ò yéé kórìíra.+ 16 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Màá na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ àwọn Filísínì,+ màá pa àwọn Kérétì rẹ́,+ màá sì run àwọn tó ṣẹ́ kù nínú àwọn tó ń gbé ní etí òkun.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sefanáyà 2:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Nítorí Gásà máa di ìlú tí a pa tì; Áṣíkẹ́lónì á sì di ahoro.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sekaráyà 9:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Áṣíkẹ́lónì á rí i, ẹ̀rù á sì bà á; Gásà yóò jẹ̀rora, Bẹ́ẹ̀ náà ni Ẹ́kírónì, torí pé ìrètí rẹ̀ ti di ìtìjú. Ọba kan yóò ṣègbé ní Gásà, Ẹnì kankan kò sì ní gbé ní Áṣíkẹ́lónì.+ 
 
-