-
Nọ́ńbà 21:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àmọ́ Síhónì ò jẹ́ kí Ísírẹ́lì gba ilẹ̀ rẹ̀ kọjá. Kàkà bẹ́ẹ̀, Síhónì kó gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ jọ, wọ́n sì lọ gbéjà ko Ísírẹ́lì ní aginjù, nígbà tí wọ́n dé Jáhásì, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í bá Ísírẹ́lì+ jà.
-
-
Àìsáyà 15:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ìdí nìyẹn tí àwọn ọkùnrin Móábù tó dira ogun fi ń kígbe ṣáá.
Ó* ń gbọ̀n rìrì.
-