- 
	                        
            
            Àìsáyà 13:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ará Arébíà kankan ò ní pàgọ́ síbẹ̀, Olùṣọ́ àgùntàn kankan ò sì ní jẹ́ kí agbo ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀. 21 Àwọn ẹranko inú aṣálẹ̀ máa dùbúlẹ̀ síbẹ̀; Àwọn ẹyẹ òwìwí máa kún ilé wọn. 
 
-