- 
	                        
            
            Àìsáyà 13:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ará Arébíà kankan ò ní pàgọ́ síbẹ̀, Olùṣọ́ àgùntàn kankan ò sì ní jẹ́ kí agbo ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 51:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        43 Àwọn ìlú rẹ̀ ti di ohun àríbẹ̀rù, ilẹ̀ tí kò lómi àti aṣálẹ̀. Ilẹ̀ tí ẹnì kankan kò ní gbé, tí èèyàn kankan kò sì ní gba ibẹ̀ kọjá.+ 
 
-