-
Sáàmù 94:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nítorí Jèhófà ò ní pa àwọn èèyàn rẹ̀ tì,+
Kò sì ní fi ogún rẹ̀ sílẹ̀.+
-
Jeremáyà 46:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Torí náà, má fòyà, ìwọ Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi,’ ni Jèhófà wí, ‘torí pé mo wà pẹ̀lú rẹ.
-
-
Sekaráyà 2:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Jèhófà yóò gba Júdà bí ìpín rẹ̀ lórí ilẹ̀ mímọ́, yóò sì tún Jerúsálẹ́mù yàn.+
-
-
-