Àìsáyà 45:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Màá fún ọ ní àwọn ìṣúra tó wà nínú òkùnkùnÀti àwọn ìṣúra tó pa mọ́ láwọn ibi tí kò hàn síta,+Kí o lè mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń fi orúkọ rẹ pè ọ́.+ Jeremáyà 50:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ẹṣin wọn àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn,Tó sì dojú kọ onírúurú àjèjì tó wà láàárín rẹ̀,Wọ́n á dà bí obìnrin.+ Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ìṣúra rẹ̀, ṣe ni wọ́n á kó wọn lọ.+
3 Màá fún ọ ní àwọn ìṣúra tó wà nínú òkùnkùnÀti àwọn ìṣúra tó pa mọ́ láwọn ibi tí kò hàn síta,+Kí o lè mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń fi orúkọ rẹ pè ọ́.+
37 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ẹṣin wọn àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn,Tó sì dojú kọ onírúurú àjèjì tó wà láàárín rẹ̀,Wọ́n á dà bí obìnrin.+ Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ìṣúra rẹ̀, ṣe ni wọ́n á kó wọn lọ.+